27 Jul, 2024

Learn Yoruba for Beginners – Short Stories : My new job

Story in Yoruba Ọ̀la ni ọjọ́ àkọ́kọ́ mi ni ibi ìṣe mi titun. Mo jí , mo wo kàlẹ́ndà mi pẹ̀lú ìdùnnú mo sì múra láti pàdé àwọn alabasise mi titun . Ní àná , mo jẹ oúnjẹ alẹ́ pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ́ mi ni ibi iṣẹ́ mi àtijọ́ . Bó ti lẹ̀ jẹ́ wípé ó jẹ ohun ibanuje ṣùgbọ́n a ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ […]

1 min read