Learn Yoruba for Beginners – Short Stories : Birthday

Story in Yoruba Orúkọ ọ̀rẹ́ mi ni Tumi ó sì má ń kọrin. N ò lọ ṣe àbẹ̀wò rẹ̀ ni ìrọ̀lẹ́ nítorí òní ni ọjọ́ ìbí rẹ̀. Àmọ́, ṣíwájú èyí, n ó ṣe àkàrà òyìnbó, n ó sì ra àwọn ohun mímu fun. Mo lérò wípé inú rẹ̀ yóò dùn nígbà tí ó bá rí. […]

Story in Yoruba

Orúkọ ọ̀rẹ́ mi ni Tumi ó sì má ń kọrin. N ò lọ ṣe àbẹ̀wò rẹ̀ ni ìrọ̀lẹ́ nítorí òní ni ọjọ́ ìbí rẹ̀. Àmọ́, ṣíwájú èyí, n ó ṣe àkàrà òyìnbó, n ó sì ra àwọn ohun mímu fun. Mo lérò wípé inú rẹ̀ yóò dùn nígbà tí ó bá .

Story in English

My friend’s name is Tumi and she can sing. I will go visit her in the evening because today is her birthday. However, before that, I have to make a cake and buy drinks for her. I hope that she will be happy when she sees it.

 

 

Endnote
Translation was done not by me but by a paid professional translator.