STORIES
A Tale of Kindness and Community
Explore the beauty of community and kindness in Yoruba culture with our heartfelt tale of sunrise bonds.
Learn Yoruba For Beginners – Stories – A Day in the Life of Tola
Enjoy a simple and engaging story about Tola’s day, perfect for beginners learning Yoruba. Discover how to use negation in everyday sentences with clear examples and helpful vocabulary.
Learn Yoruba for Beginners – Stories – Akin and the Lion’s Fight
Akin ati Ija Ekun (Akin and the Lion’s Fight) Ọjọ kan, ni igba kan ri, ni abule kekere kan ti a npe ni Ilé-Ìfẹ́, ọmọdékunrin kan wa ti orukọ rẹ̀ jẹ Akin. Akin jẹ́ ọmọ ti o lẹwa ati ọlọgbọn, o si fẹran lati ran ẹbi rẹ ati awọn ọrẹ rẹ lọwọ. Ọjọ kan, baba […]
Learn Yoruba for Beginners – Short Stories : Birthday
Story in Yoruba Orúkọ ọ̀rẹ́ mi ni Tumi ó sì má ń kọrin. N ò lọ ṣe àbẹ̀wò rẹ̀ ni ìrọ̀lẹ́ nítorí òní ni ọjọ́ ìbí rẹ̀. Àmọ́, ṣíwájú èyí, n ó ṣe àkàrà òyìnbó, n ó sì ra àwọn ohun mímu fun. Mo lérò wípé inú rẹ̀ yóò dùn nígbà tí ó bá rí. […]
Learn Yoruba for Beginners – Short Stories : My new job
Story in Yoruba Ọ̀la ni ọjọ́ àkọ́kọ́ mi ni ibi ìṣe mi titun. Mo jí , mo wo kàlẹ́ndà mi pẹ̀lú ìdùnnú mo sì múra láti pàdé àwọn alabasise mi titun . Ní àná , mo jẹ oúnjẹ alẹ́ pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ́ mi ni ibi iṣẹ́ mi àtijọ́ . Bó ti lẹ̀ jẹ́ wípé ó jẹ ohun ibanuje ṣùgbọ́n a ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ […]