Learn Yoruba for Beginners – Short Stories : My new job
1 min read

Learn Yoruba for Beginners – Short Stories : My new job

Story in Yoruba

Ọ̀la ni ọjọ́ àkọ́kọ́ mi ni ibi ìṣe mi titun. Mo jí , mo wo kàlẹ́ndà mi pẹ̀lú ìdùnnú mo sì múra láti pàdé àwọn alabasise mi titun . Ní àná , mo jẹ oúnjẹ alẹ́ pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ́ mi ni ibi iṣẹ́ mi àtijọ́ . Bó ti lẹ̀ jẹ́ wípé ó jẹ ohun ibanuje ṣùgbọ́n a ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbádùn.

Story in English

Tomorrow is my first day at my new job. I wake up, look at my calendar excitedly and prepare to meet my new colleagues. Yesterday, I had dinner with my friends at my old company. Although it was sad, we had lots of fun.

Endnote
Translation was done not by me but by a paid professional translator.