21 Jul, 2024

Learn Yoruba for Beginners – Stories – Akin and the Lion’s Fight

Akin ati Ija Ekun (Akin and the Lion’s Fight) Ọjọ kan, ni igba kan ri, ni abule kekere kan ti a npe ni Ilé-Ìfẹ́, ọmọdékunrin kan wa ti orukọ rẹ̀ jẹ Akin. Akin jẹ́ ọmọ ti o lẹwa ati ọlọgbọn, o si fẹran lati ran ẹbi rẹ ati awọn ọrẹ rẹ lọwọ. Ọjọ kan, baba […]

6 mins read

Learn Yoruba for Beginners – Short Stories : My new job

Story in Yoruba Ọ̀la ni ọjọ́ àkọ́kọ́ mi ni ibi ìṣe mi titun. Mo jí , mo wo kàlẹ́ndà mi pẹ̀lú ìdùnnú mo sì múra láti pàdé àwọn alabasise mi titun . Ní àná , mo jẹ oúnjẹ alẹ́ pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ́ mi ni ibi iṣẹ́ mi àtijọ́ . Bó ti lẹ̀ jẹ́ wípé ó jẹ ohun ibanuje ṣùgbọ́n a ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ […]

1 min read